O. Daf 54:7
O. Daf 54:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nítorí tí ó yọ mí kúrò nínú ibi gbogbo ojú mi ti wo ìṣẹ́gun lórí ọ̀tá mi.
Pín
Kà O. Daf 54O. Daf 54:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori o ti yọ mi kuro ninu iṣẹ́ gbogbo: oju mi si ri ifẹ rẹ̀ lara awọn ọta mi.
Pín
Kà O. Daf 54