O. Daf 54:6
O. Daf 54:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èmí yóò rú ẹbọ àtinúwá sí ọ, èmi yóò yin orúkọ rẹ, OLúWA, nítorí tí ó dára.
Pín
Kà O. Daf 54O. Daf 54:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o rubọ atinuwa si ọ: Oluwa, emi o yìn orukọ rẹ; nitoriti o dara.
Pín
Kà O. Daf 54