O. Daf 51:2
O. Daf 51:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Wẹ̀ mi li awẹmọ́ kuro ninu aiṣedede mi, ki o si wẹ̀ mi nù kuro ninu ẹ̀ṣẹ mi.
Pín
Kà O. Daf 51O. Daf 51:2 Yoruba Bible (YCE)
Wẹ̀ mí mọ́ kúrò ninu àìdára mi, kí o sì wẹ̀ mí kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ mi!
Pín
Kà O. Daf 51