O. Daf 51:10-12
O. Daf 51:10-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Da aiya titun sinu mi, Ọlọrun; ki o si tún ọkàn diduroṣinṣin ṣe sinu mi. Máṣe ṣa mi tì kuro niwaju rẹ; ki o má si ṣe gbà Ẹmi mimọ́ rẹ lọwọ mi. Mu ayọ̀ igbala rẹ pada tọ̀ mi wá; ki o si fi ẹmi omnira rẹ gbé mi duro.
Pín
Kà O. Daf 51O. Daf 51:10-12 Yoruba Bible (YCE)
Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọrun, kí o sì fi ẹ̀mí ọ̀tun ati ẹ̀mí ìṣòótọ́ sí mi lọ́kàn. Má ta mí nù kúrò lọ́dọ̀ rẹ, má sì gba Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ lọ́wọ́ mi. Dá ayọ̀ ìgbàlà rẹ pada fún mi, kí o sì fi ẹ̀mí àtiṣe ìfẹ́ rẹ gbé mi ró.
Pín
Kà O. Daf 51