O. Daf 45:17
O. Daf 45:17 Yoruba Bible (YCE)
N óo mú kí á máa ki oríkì rẹ láti ìran dé ìran; nítorí náà àwọn eniyan yóo máa yìn ọ́ lae ati laelae.
Pín
Kà O. Daf 45O. Daf 45:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o ma ṣe orukọ rẹ ni iranti ni iran gbogbo: nitorina li awọn enia yio ṣe ma yìn ọ lai ati lailai.
Pín
Kà O. Daf 45