O. Daf 33:18
O. Daf 33:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kiye si i, oju Oluwa mbẹ lara awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, lara awọn ti nreti ninu ãnu rẹ̀
Pín
Kà O. Daf 33O. Daf 33:18 Yoruba Bible (YCE)
Wò ó! OLUWA ń ṣọ́ àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, àní àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀
Pín
Kà O. Daf 33