O. Daf 32:8
O. Daf 32:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o fi ẹsẹ̀ rẹ le ọ̀na, emi o si kọ́ ọ li ọ̀na ti iwọ o rìn: emi o ma fi oju mi tọ́ ọ.
Pín
Kà O. Daf 32O. Daf 32:8 Yoruba Bible (YCE)
N óo kọ́ ọ, n óo sì tọ́ ọ sí ọ̀nà tí o óo rìn; n óo máa gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn; n óo sì máa mójútó ọ.
Pín
Kà O. Daf 32