O. Daf 27:13-14
O. Daf 27:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn emi ti gbagbọ lati ri ire Oluwa ni ilẹ alãye. Duro de Oluwa; ki o si tújuka, yio si mu ọ li aiya le: mo ni, duro de Oluwa.
Pín
Kà O. Daf 27O. Daf 27:13-14 Yoruba Bible (YCE)
Mo gbàgbọ́ pé n óo rí oore OLUWA gbà ní ilẹ̀ alààyè. Dúró de OLUWA, ṣe bí akin, kí o sì mú ọkàn gírí, àní, dúró de OLUWA.
Pín
Kà O. Daf 27