O. Daf 26:2-3
O. Daf 26:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Wadi mi, Oluwa, ki o si ridi mi; dán inu mi ati ọkàn mi wò. Nitoriti iṣeun-ifẹ rẹ mbẹ niwaju mi: emi si ti nrìn ninu otitọ rẹ.
Pín
Kà O. Daf 26O. Daf 26:2-3 Yoruba Bible (YCE)
Yẹ̀ mí wò, OLUWA, dán mi wò; yẹ inú mi wò, sì ṣe akiyesi ọkàn mi. Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni mo tẹjúmọ́, mo sì ń fi òtítọ́ bá ọ rìn.
Pín
Kà O. Daf 26O. Daf 26:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Wadi mi, Oluwa, ki o si ridi mi; dán inu mi ati ọkàn mi wò. Nitoriti iṣeun-ifẹ rẹ mbẹ niwaju mi: emi si ti nrìn ninu otitọ rẹ.
Pín
Kà O. Daf 26