O. Daf 20:7
O. Daf 20:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Awọn ẹlomiran gbẹkẹle kẹkẹ́, awọn ẹlomiran le ẹṣin; ṣugbọn awa o ranti orukọ Oluwa Ọlọrun wa.
Pín
Kà O. Daf 20O. Daf 20:7 Yoruba Bible (YCE)
Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀lé kẹ̀kẹ́ ogun, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀lé ẹṣin, ṣugbọn ní tiwa, àwa gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLUWA Ọlọrun wa.
Pín
Kà O. Daf 20