O. Daf 2:6-7
O. Daf 2:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn mo ti fi Ọba mi jẹ lori Sioni, òke mimọ́ mi. Emi o si rohin ipinnu Oluwa: O ti wi fun mi pe, Iwọ li Ọmọ mi, loni ni mo bi ọ.
Pín
Kà O. Daf 2Ṣugbọn mo ti fi Ọba mi jẹ lori Sioni, òke mimọ́ mi. Emi o si rohin ipinnu Oluwa: O ti wi fun mi pe, Iwọ li Ọmọ mi, loni ni mo bi ọ.