O. Daf 19:14
O. Daf 19:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Jẹ ki ọ̀rọ ẹnu mi, ati iṣaro ọkàn mi, ki o ṣe itẹwọgba li oju rẹ, Oluwa, agbara mi, ati oludande mi.
Pín
Kà O. Daf 19O. Daf 19:14 Yoruba Bible (YCE)
Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi, ati àṣàrò ọkàn mi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ, OLUWA ibi ààbò mi ati olùràpadà mi.
Pín
Kà O. Daf 19