O. Daf 149:1
O. Daf 149:1 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ yin OLUWA! Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́.
O. Daf 149:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ fi iyìn fun Oluwa. Ẹ kọ orin titun si Oluwa, ati iyìn rẹ̀ ninu ijọ awọn enia-mimọ́.