Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 145:8-9

O. Daf 145:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)

Olore-ọfẹ li Oluwa, o kún fun ãnu; o lọra lati binu, o si li ãnu pupọ̀. Oluwa ṣeun fun ẹni gbogbo; iyọ́nu rẹ̀ si mbẹ lori iṣẹ rẹ̀ gbogbo.

Pín
Kà O. Daf 145

O. Daf 145:8-9 Yoruba Bible (YCE)

Aláàánú ni OLUWA, olóore sì ni; kì í yára bínú, ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀. OLUWA ṣeun fún gbogbo eniyan, àánú rẹ̀ sì ń bẹ lórí gbogbo ohun tí ó dá.

Pín
Kà O. Daf 145

O. Daf 145:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Olóore-ọ̀fẹ́ ni OLúWA àti aláàánú ó lọ́ra láti bínú ó sì ní ìfẹ́ púpọ̀. OLúWA dára sí ẹni gbogbo; ó ní àánú lórí ohun gbogbo tí ó dá.

Pín
Kà O. Daf 145
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò