O. Daf 140:2-3
O. Daf 140:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti nrò ìwa-buburu ni inu wọn; nigbagbogbo ni nwọn nrú ìja soke si mi. Nwọn ti pọ́n ahọn wọn bi ejo; oro pãmọlẹ mbẹ li abẹ ète wọn.