O. Daf 139:8
O. Daf 139:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Bí èmi bá gòkè lọ sí ọ̀run, ìwọ wà níbẹ̀; bí èmí ba sì tẹ́ ẹní mi ní ipò òkú, kíyèsi i, ìwọ wà níbẹ̀ pẹ̀lú.
O. Daf 139:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi emi ba gòke lọ si ọrun, iwọ wà nibẹ: bi emi ba si tẹ́ ẹni mi ni ipò okú, kiyesi i, iwọ wà nibẹ.