O. Daf 139:23
O. Daf 139:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọlọrun, wadi mi, ki o si mọ̀ aiya mi: dán mi wò, ki o si mọ̀ ìro-inu mi
O. Daf 139:23 Yoruba Bible (YCE)
Wádìí mi, Ọlọrun, kí o mọ ọkàn mi; yẹ̀ mí wò, kí o sì mọ èrò ọkàn mi.