Bi Oluwa tilẹ ga, sibẹ o juba awọn onirẹlẹ; ṣugbọn agberaga li o mọ̀ li òkere rére.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLUWA ga lọ́lá, ó ka àwọn onírẹ̀lẹ̀ sí, ṣugbọn ó mọ àwọn onigbeeraga lókèèrè.
Bí OLúWA tilẹ̀ ga, síbẹ̀ ó júbà àwọn onírẹ̀lẹ̀; ṣùgbọ́n agbéraga ni ó mọ̀ ní òkèrè réré.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò