O. Daf 134:1-3
O. Daf 134:1-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ kiyesi i, ẹ fi ibukún fun Oluwa, gbogbo ẹnyin iranṣẹ Oluwa, ti nduro ni ile Oluwa li oru. Ẹ gbé ọwọ nyin soke si ibi-mimọ́, ki ẹ si fi ibukún fun Oluwa. Oluwa ti o da ọrun on aiye, ki o busi i fun ọ lati Sioni wá.