Bi ìri Hermoni ti o ṣàn sori òke Sioni: nitori nibẹ ni Oluwa gbe paṣẹ ibukún, ani ìye lailai.
Ó dàbí ìrì òkè Herimoni, tí ó sẹ̀ sórí òkè Sioni. Níbẹ̀ ni OLUWA ti ṣe ìlérí ibukun, àní, ìyè ainipẹkun.
Bí ìrì Hermoni tí o sàn sórí òkè Sioni. Nítorí níbẹ̀ ní OLúWA gbé pàṣẹ ìbùkún, àní ìyè láéláé.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò