Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 13:1-2

O. Daf 13:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)

IWỌ o ti gbagbe mi pẹ to, Oluwa, lailai? iwọ o ti pa oju rẹ mọ́ pẹ to kuro lara mi? Emi o ti ma gbìmọ li ọkàn mi pẹ to? ti emi o ma ni ibinujẹ li ọkàn mi lojojumọ? ọta mi yio ti gberaga sori mi pẹ to?

Pín
Kà O. Daf 13

O. Daf 13:1-2 Yoruba Bible (YCE)

Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni? Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi? Títí di ìgbà wo ni ọkàn mi yóo gbọgbẹ́ tí ìbànújẹ́ yóo gba ọkàn mi kan, ní gbogbo ìgbà? Títí di ìgbà wo ni àwọn ọ̀tá mi yóo máa yọ̀ mí?

Pín
Kà O. Daf 13

O. Daf 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Yóò ti pẹ́ tó, OLúWA? Ìwọ o ha gbàgbé mi títí láé? Yóò tí pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa fi ojú rẹ pamọ́ fún mi? Yóò ti pẹ́ tó tí èmi ó máa bá èrò mi jà, àti ní ojoojúmọ́ ni èmi ń ní ìbànújẹ́ ní ọkàn mi? Yóò ti pẹ́ tó tí àwọn ọ̀tá mi yóò máa borí mi?

Pín
Kà O. Daf 13
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò