Bi o ṣe ti iru awọn ti nwọn yà si ipa ọ̀na wiwọ wọn: Oluwa yio jẹ ki wọn lọ pẹlu awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ: ṣugbọn alafia yio wà lori Israeli.
Ṣugbọn OLUWA yóo fi irú ìyà àwọn aṣebi jẹ àwọn tí ó yà sí ọ̀nà àìtọ́. Alaafia fún Israẹli!
Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; OLúWA yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀. Ṣùgbọ́n àlàáfíà yóò wà lórí Israẹli.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò