O. Daf 122:6-8
O. Daf 122:6-8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbadura fun alafia Jerusalemu: awọn ti o fẹ ọ yio ṣe rere. Ki alafia ki o wà ninu odi rẹ, ati ire ninu ãfin rẹ. Nitori awọn arakunrin ati awọn ẹgbẹ mi, emi o wi nisisiyi pe, Ki alafia ki o wà ninu rẹ!