GBÀ-NI Oluwa; nitori awọn ẹni ìwa-bi-Ọlọrun dasẹ̀; nitori awọn olõtọ dasẹ̀ kuro ninu awọn ọmọ enia.
Gbani, OLUWA; nítorí àwọn olódodo kò sí mọ́; àwọn olóòótọ́ ti pòórá láàrin àwọn ọmọ eniyan.
Ràn wá lọ́wọ́, OLúWA, nítorí ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run kò sí mọ́; Olóòtítọ́ tí pòórá kúrò láàrín àwọn ènìyàn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò