Ó mú wọn jáde kúrò nínú òkùnkùn àti òjìji ikú, ó sì fa irin tí wọ́n fi dè wọ́n já.
O mu wọn jade kuro ninu òkunkun ati ojiji ikú, o si fa ìde wọn ja.
Ó yọ wọ́n kúrò ninu òkùnkùn ati ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn, ó sì já ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ wọn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò