O. Daf 107:1-2
O. Daf 107:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa, nitori ti o ṣeun: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai. Jẹ ki awọn ẹni-irapada Oluwa ki o wi bẹ̃, ẹniti o rà pada kuro ni ọwọ ọta nì.
O. Daf 107:1-2 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. Kí àwọn tí OLUWA ti rà pada kí ó wí bẹ́ẹ̀, àní, àwọn tí ó yọ kúrò ninu ìpọ́njú