O. Daf 104:1-2
O. Daf 104:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Yin OLúWA, ìwọ ọkàn mi. OLúWA Ọlọ́run mi, ìwọ tóbi jọjọ; ọlá àti ọláńlá ni ìwọ wọ̀ ní aṣọ. Ìwọ fi ìmọ́lẹ̀ bo ara rẹ gẹ́gẹ́ bí aṣọ; ó tẹ ọ̀run bí títẹ́ ẹní
O. Daf 104:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
FI ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi. Oluwa, Ọlọrun mi, iwọ tobi jọjọ: ọlá ati ọla-nla ni iwọ wọ̀ li aṣọ. Ẹniti o fi imọlẹ bora bi aṣọ: ẹniti o ta ọrun bi aṣọ tita