Eyi li a o kọ fun iran ti mbọ̀; ati awọn enia ti a o da yio ma yìn Oluwa.
Kí ẹ kọ èyí sílẹ̀ fún ìran tí ń bọ̀, kí àwọn ọmọ tí a kò tíì bí lè máa yin OLUWA
Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀, àwọn ènìyàn tí a kò tí ì dá yóò yin OLúWA
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò