Ẹniti o ba nṣe ẹ̀tan, kì o gbe inu ile mi: ẹniti o ba nsẹke kì yio duro niwaju mi.
Ẹlẹ́tàn kankan kò ní gbé inú ilé mi; bẹ́ẹ̀ ni òpùrọ́ kankan kò ní dúró níwájú mi.
Ẹni tí ó bá ń ṣe ẹ̀tàn, kì yóò gbé ilé mi, kò sí ẹni tí ń ṣèké tí yóò dúró ní iwájú mi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò