O. Daf 101:3
O. Daf 101:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èmi kì yóò gbé ohun búburú sí iwájú mi: iṣẹ́ àwọn tí ó yapa ni èmi kórìíra. Wọn kì yóò rọ̀ mọ́ mi.
O. Daf 101:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi ki yio gbé ohun buburu siwaju mi: emi korira iṣẹ awọn ti o yapa, kì yio fi ara mọ mi.