Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Owe 4:3YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitoripe ọmọ baba mi li emi iṣe, ẹni-ikẹ́ ati olufẹ li oju iya mi.
Pín
Owe 4YBCVOwe 4:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo jẹ́ ọ̀dọ́mọkùnrin ní ilé baba à mí, mo jẹ́ èwe, tí mo sì jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo lọ́wọ́ ìyá mi.
Pín
Owe 4BMYOOwe 4:3YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí mo wà ní ọmọde lọ́dọ̀ baba mi, tí mo jẹ́ ẹni ìkẹ́, ọ̀kan ṣoṣo lọ́wọ́ ìyá mi
Pín
Owe 4YCE