Owe 31:31
Owe 31:31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Fi fun u ninu eso-iṣẹ ọwọ rẹ̀; jẹ ki iṣẹ ọwọ ara rẹ̀ ki o si yìn i li ẹnu-bodè.
Pín
Kà Owe 31Owe 31:31 Yoruba Bible (YCE)
Fún un ninu èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, jẹ́ kí wọn máa yìn ín lẹ́nu ibodè nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.
Pín
Kà Owe 31