Máṣe fi iranṣẹ sùn oluwa rẹ̀, ki o má ba fi ọ bu, ki iwọ má ba jẹbi.
Má ba iranṣẹ jẹ́ lójú ọ̀gá rẹ̀, kí ó má baà gbé ọ ṣépè, kí o sì di ẹlẹ́bi.
“Má ṣe ba ìránṣẹ́ lórúkọ jẹ́ lọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀, kí ó má ba fi ọ́ bú, kí ìwọ má ba jẹ̀bi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò