Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Owe 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitori ọjọ gigùn, ati ẹmi gigùn, ati alafia ni nwọn o fi kún u fun ọ.

Owe 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí ọjọ́ gígùn, ẹ̀mí gígùn, àti àlàáfíà, ni wọn yóò fi kùn un fún ọ.

Owe 3:2YCE(Yoruba Bible)

nítorí wọn óo fún ọ ní ẹ̀mí gígùn ati ọpọlọpọ alaafia.