Owe 21:2
Owe 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Gbogbo ọ̀nà ènìyàn dàbí i pé ó dára lójú rẹ̀ ṣùgbọ́n, OLúWA ló ń díwọ̀n ọkàn.
Pín
Kà Owe 21Owe 21:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo ọ̀na enia li o dara li oju ara rẹ̀: ṣugbọn Oluwa li o nṣe amọ̀na ọkàn.
Pín
Kà Owe 21Owe 21:2 Yoruba Bible (YCE)
Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó dára lójú ara rẹ̀, ṣugbọn ọkàn ni OLUWA ń wò.
Pín
Kà Owe 21