Owe 19:8-9
Owe 19:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o gbọ́n, o fẹ ọkàn ara rẹ̀: ẹniti o pa oye mọ́ yio ri rere. Ẹlẹri eke kì yio lọ laijiya, ẹniti o si nṣeke yio ṣegbe.
Pín
Kà Owe 19Ẹniti o gbọ́n, o fẹ ọkàn ara rẹ̀: ẹniti o pa oye mọ́ yio ri rere. Ẹlẹri eke kì yio lọ laijiya, ẹniti o si nṣeke yio ṣegbe.