Owe 19:4 - Compare All Versions
Owe 19:4 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrọ̀ fà ọrẹ́ pupọ; ṣugbọn talaka di yiyà kuro lọdọ aladugbo rẹ̀.
Pín
Owe 19 YBCVOwe 19:4 YCE (Yoruba Bible)
Ọrọ̀ a máa mú kí eniyan ní ọpọlọpọ ọ̀rẹ́ titun, ṣugbọn àwọn ọ̀rẹ́ talaka a máa kọ̀ ọ́ sílẹ̀.
Pín
Owe 19 YCEOwe 19:4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀; ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ tálákà tún kọ̀ ọ́ sílẹ̀.
Pín
Owe 19 BMYO