Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Owe 18:23YBCV(Bibeli Mimọ)

Talaka a ma bẹ̀ ẹ̀bẹ; ṣugbọn ọlọrọ̀ a ma fi ikanra dahùn.

Owe 18:23BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú, ṣùgbọ́n ọlọ́rọ̀ a dáhùn pẹ̀lú ìkanra.

Owe 18:23YCE(Yoruba Bible)

Ẹ̀bẹ̀ ni talaka bẹ̀, ṣugbọn ọlọ́rọ̀ á dáhùn tìkanra-tìkanra.