Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Owe 18:19YBCV(Bibeli Mimọ)

Arakunrin ti a ṣẹ̀ si, o ṣoro jù ilu olodi lọ: ìja wọn si dabi ọpá idabu ãfin.

Owe 18:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Arákùnrin tí a ṣẹ̀ sí ṣòro yípadà ju ìlú olódi lọ, ìjà wọ sì dàbí ọ̀pá ìdábùú ààfin.

Owe 18:19YCE(Yoruba Bible)

Ọkàn arakunrin tí eniyan bá ṣẹ̀ a máa le bí ìlú olódi, àríyànjiyàn sì dàbí ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn ilé ìṣọ́.