Owe 18:1-2
Owe 18:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ẸNITI o yà ara rẹ̀ sọtọ̀ yio lepa ifẹ ara rẹ̀, yio si kọju ìja nla si ohunkohun ti iṣe ti oye. Aṣiwère kò ni inu-didùn si imoye, ṣugbọn ki o le fi aiya ara rẹ̀ hàn.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:1-2 Yoruba Bible (YCE)
Onímọ-tara-ẹni-nìkan ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀, láti tako ìdájọ́ òtítọ́. Òmùgọ̀ kò ní inú dídùn sí ìmọ̀, àfi kí ó ṣá máa sọ èrò ọkàn rẹ̀.
Pín
Kà Owe 18