Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Owe 17:28

Owe 17:28 Bibeli Mimọ (YBCV)

Lõtọ, aṣiwère, nigbati o ba pa ẹnu rẹ̀ mọ́, a kà a si ọlọgbọ́n; ẹniti o ba pa ẹnu rẹ̀ mọ́ si li amoye.

Pín
Kà Owe 17

Owe 17:28 Yoruba Bible (YCE)

A máa ka òmùgọ̀ pàápàá kún ọlọ́gbọ́n, bí ó bá pa ẹnu rẹ̀ mọ́, olóye ni àwọn eniyan yóo pè é, bí ó bá panu mọ́ tí kò sọ̀rọ̀.

Pín
Kà Owe 17

Owe 17:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Kódà aláìgbọ́n máa ń dàbí ọlọ́gbọ́n bí ó bá dákẹ́ àti bí olóye bí ó bá fètèmétè.

Pín
Kà Owe 17

Owe 17:28

Owe 17:28 YBCVOwe 17:28 YBCVOwe 17:28 YBCV
Pín
Kà Orí tí ó kún
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò