Owe 17:27
Owe 17:27 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ó bá ní ìmọ̀ a máa kó ahọ́n rẹ̀ ní ìjánu, ẹni tí ó bá jẹ́ olóye eniyan a máa ṣe jẹ́ẹ́.
Pín
Kà Owe 17Owe 17:27 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o ni ìmọ, a ṣẹ́ ọ̀rọ rẹ̀ kù: ọlọkàn tutu si li amoye enia.
Pín
Kà Owe 17