Owe 17:24
Owe 17:24 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ó ní òye a máa tẹjúmọ́ ọgbọ́n, ṣugbọn ojú òmùgọ̀ kò gbé ibìkan, ó ń wo òpin ilẹ̀ ayé.
Pín
Kà Owe 17Owe 17:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọgbọ́n wà niwaju ẹniti o moye; ṣugbọn oju aṣiwère mbẹ li opin ilẹ̀-aiye.
Pín
Kà Owe 17