Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Owe 14:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọgbọ́n amoye ni ati moye ọ̀na rẹ̀: ṣugbọn iwere awọn aṣiwere li ẹ̀tan.
Owe 14:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọgbọ́n olóye ni láti ronú jinlẹ̀ nípa ọ̀nà wọn ṣùgbọ́n ìwà òmùgọ̀ aṣiwèrè ni ìtànjẹ.
Owe 14:8YCE(Yoruba Bible)
Ohun tí ó jẹ́ ọgbọ́n fún ọlọ́gbọ́n ni pé kí ó kíyèsí ọ̀nà ara rẹ̀, ṣugbọn àìmòye àwọn òmùgọ̀ kún fún ìtànjẹ.