Ẹniti o nrìn ni iduroṣiṣin rẹ̀ o bẹ̀ru Oluwa: ṣugbọn ẹniti o ṣe arekereke li ọ̀na rẹ̀, o gàn a.
Ẹni tí ń rìn pẹlu òótọ́ inú yóo bẹ̀rù OLUWA, ṣugbọn ẹni tí ń rin ìrìn ségesège yóo kẹ́gàn rẹ̀.
Ẹni tí ń rìn déédé bẹ̀rù OLúWA, ṣùgbọ́n ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ kò tọ́ kẹ́gàn OLúWA.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò