Owe 14:17-19
Owe 14:17-19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o ba tete binu, huwa wère; ẹni eletè buburu li a korira. Awọn òpe jogun iwère; ṣugbọn awọn amoye li a fi ìmọ de li ade. Awọn ẹni-buburu tẹriba niwaju awọn ẹnirere; ati awọn enia buburu li ẹnu-ọ̀na awọn olododo.
Pín
Kà Owe 14