Owe 13:6
Owe 13:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:6 Yoruba Bible (YCE)
Òdodo a máa dáàbò bo ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ bá tọ́, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ a máa bi eniyan burúkú ṣubú.
Pín
Kà Owe 13