Owe 13:5-6
Owe 13:5-6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olododo korira ẹ̀tan; ṣugbọn enia buburu mu ni hu ìwa irira on itiju. Ododo pa aduro-ṣinṣin li ọ̀na mọ́; ṣugbọn ìwa-buburu ni imuni ṣubu sinu ẹ̀ṣẹ.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:5-6 Yoruba Bible (YCE)
Olóòótọ́ a máa kórìíra èké, ṣugbọn eniyan burúkú a máa hùwà ìtìjú ati àbùkù. Òdodo a máa dáàbò bo ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ bá tọ́, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ a máa bi eniyan burúkú ṣubú.
Pín
Kà Owe 13