Owe 13:4
Owe 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkan kan, ṣùgbọ́n ọkàn àwọn ti kì í ṣe ọ̀lẹ rí ìtẹ́lọ́rùn.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọkàn ọlẹ nfẹ, kò si ri nkan; ṣugbọn ọkàn awọn alãpọn li a o mu sanra.
Pín
Kà Owe 13