Owe 13:24
Owe 13:24 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí kì í bá na ọmọ rẹ̀ kò fẹ́ràn rẹ̀, ṣugbọn ẹni tí ó fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ yóo máa bá a wí.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o ba fà ọwọ paṣan sẹhin, o korira ọmọ rẹ̀; ṣugbọn ẹniti o fẹ ẹ a ma tète nà a.
Pín
Kà Owe 13